Àbáwọlé – BBC News Yorùbá

Ibí yìí lo ti máa rí ojúlówó ìròyìn àjáàbalẹ̀ lórí ojú ọjọ́, ètò ọrọ̀ ajé, ìdánilárayá, òṣèlú, ìròyìn àgbáyé ní ìṣẹ́jú kan àtàwọn míràn. BBC Yorùbá máa ń ṣe ìròyìn àkànṣe, fídíò, ọ̀rọ̀ ẹnu, fọ́tò tó jojú ní gbèsè àti itọ́ni onísọ̀rọ̀-ǹ-gbèsì tó dáńtọ́

BBC News, Yorùbá – Ìròyìn

Ìròyìn tó ṣe kókó

Móríwú

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

  • Aworan iwọde ni Oyo00:37 Fídíò, Aráàlú fárígá, ṣèwọ́de ní Ibadan tako ìjọba lórí bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ tí wọ́n jí gbé ṣì ṣe wà ní àhámọ́ , Duration 0,37
  • Aworan bi omi okun se ru titi de odidi ile kan ni Ayetoro02:45 Fídíò, Ìfúpá àwọn èèyàn Ayetoro l‘Ondo ń ga sí, torí bí òkun ṣe ń ya wọ ìlú, gbé iléẹ̀kọ́, ilégbèé, iléeṣẹ́, ilẹ̀ àti ibojì òkù lọ, Duration 2,45
  • Agolo ohun mimu Energy Drink kan01:26 Fídíò, Wo àkóbá mọ́kànlá tí ohun mímu ‘Energy Drinks’ le ṣe fún àgọ́ ara rẹ, Duration 1,26
  • Yara ikawe ti iji ojo lile si lọ04:32 Fídíò, Ìjì òjò líle sí òrúlé, da ògiri wó nílé ẹ̀kọ́ girama ọgbọ̀n l‘Ogbomoso, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ n kẹ́kọ̀ọ́ lábẹ́ ilé àlàpa, Duration 4,32
  • Erekusu Ẹ̀bá to wa lẹb omi nla02:16 Fídíò, “Ìjọba rí epo rọ̀bì ní ìlú wa àmọ́ a kò jàǹfààní kankan, kò sí omi, iná, ojú ọ̀nà, ààbò, iléẹ̀kọ́ àti ilé ìwòsàn”, Duration 2,16
  • Aworan akọle ileewe naa03:22 Fídíò, Àwọn ajínigbé tó kó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yìnbọn sí wa nígbà tí a ń lé wọn wọgbó ìbọn wà kò ràn wọ́n ni – Àwọn ọlọ́dẹ ìlú Esinele, Duration 3,22
  • Aworan02:31 Fídíò, Wo ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa àrùn Ebola tuntun, Duration 2,31
  • Aworan ere Oronna02:34 Fídíò, Oronna, jagunjagun tó gbéra láti Oyo lọ tẹ ìlú Ilaro dó, Duration 2,34
  • Idamu Industry02:21 Fídíò, Olaniyan ‘Idamu Industry’ Oluwatosin jẹ́wọ́ pé ẹnu nìkan kọ́ lòun ní lórí ètò ‘Ṣé o láyà?’, Duration 2,21
  • Aworan Ogboriefon05:24 Fídíò, Agbolé Akọni: Mọ̀ nípa Ogboriefon, akọni tí wọ́n rí he lórí àkìtàn tó di jagunjagun ńlá, Duration 5,24
  • Aworan oni ipele meji ti loko laya n jo ninu ile ni ipele kini l'oke ti obinrin kan si n soro ni ipele ti isale01:40 Fídíò, Wo bí hòmóònù ṣe ń mú àyípadà bá ìhùwàsí àwọn obìnrin ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀, Duration 1,40
  • Abayomi Alvin wọ asọ shaati dudu, o de fila bẹnti gọ, o si fi ẹgba ọrun sọrun ati igo soju04:05 Fídíò, Mo ti fẹ́ obìnrin rí lágbo tíátà àmọ́ kò ní àṣeyọrí, owó, obìnrin àti agbára ló ń fa gbajúmọ̀ ọkùnrin ṣubú – Abayomi Alvin, Duration 4,05

BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp

Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ

Darapọ̀ mọ́ wa lórí WhatsApp

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ

  1. 1Fayose nílò àdúrà, ẹ ṣàánú rẹ̀ – Makinde da padà lẹ́yìn tí Fayose ní ó lè jẹ́ òun ló ṣagbátẹrù ìjínigbé Ogbomoso
  2. 2Ìjàmbá ọkọ̀ ló fa ikú òṣèré tíátà, ‘Janmole’ – Mr Latin
  3. 3Aráàlú fárígá, àwọn olùwọ́de já géètì sẹkitéríàtì ìjọba, ìpè fún ìtúsílẹ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ tí wọ́n jí gbé l’Ogbomoso káàkiri Nàìjíríà
  4. 4Èyí làwọn olóṣèlú tó fẹ́ dupò ààrẹ ní 2027 tórúkọ wọn gbilẹ̀ jù
  5. 5Àwọn ilé ẹ̀kọ́ tilẹ̀kùn wọn pa l’Osun nítorí ìròyìn pé agbébọn wọ ìlú, Adeleke ní kò sí ohun tó jọ bẹ́ẹ̀
  6. 6Àwọn wo ló fẹ́ wú ère ẹlẹ́sẹ̀ ayò, Lionel Messi, àti pé kí ló fàá?
  7. 7Aṣọ kan ló kù lọ́rùn àwọn òbí mi nítorí ẹ̀kọ́ mi, ètò ẹ̀yáwókàwé NELFUND ló kó mi yọ láti kẹ́kọ̀ọ́ jáde – Oladepo Gbenga akẹ́kọ̀ọ́ tó mókè jùlọ ní fásitì LAUTECH
  8. 8”Èyi ni ipa tí Bàba-bàbá mi kó nínú ogun abẹ́lé Biafra”-Meji Alabi, gbajúmọ̀ adarí orin
  9. 9‘A ò lè lọ síbi iṣẹ́ mọ́ torí àwọn olùkọ́ àtàwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n jí gbé l’Ogbomoso,’ àwọn olùkọ́ ṣèfẹ̀hónúhàn l’Oyo
  10. 10Àgbà òṣèré tíátà, Feso Oyewole jáde láyé

About The Author

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *